Haruna Iṣọ́lá àti Ẹgbẹ́ Majority ìlú Cotonou?

Haruna Iṣọ́láTa lo mọ nkan ti o ṣelẹ́ si ẹgbẹ́ ọmọ Yorùbá ti o wà ni Cotonou – “Ẹgbẹ́ Majority“, ti Bàbá Haruna Iṣọ́lá fi kọrin ni ọdún 1982 nínú àwo (orin) ti wọn pe ní “Ẹgbẹ́ Ọrẹdẹgbẹ́, Kaduna”?
Ṣe Ẹgbẹ́ Majority ṣi wà ni ìlú Cotonou, ni orílẹ̀-ede Benin, lóni?

Cotonou

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter

Ìkíni Yorùbá ní orílẹ̀-èdè Bẹ̀nẹ̀ (Benin) nílẹ̀ Idàhọ̀mi

Ìtọ́ka sí ayélújára ní èdè Faransé (Français) ńibí ti wọn ti tò lẹ́sẹẹsẹ oríṣiríṣi ìkíni Yorùbá to le ní igba (200), ti wọn lo ní orílẹ̀-èdè Bẹ̀nẹ̀n (Benin) nílẹ̀ Idàhọ̀mi :-

http://www.beninensis.net/Salutations_Yoruba.htm

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter