|
|||||
Èlò-ìṣẹ́ ẹ̀rọ ibanisọ̀rọ̀ alagbéka fún oríṣiríṣi orúkọ (16,452) ọmọ YorùbáÈrò ọkàn ènìyàn (3) nípa Èlò-ìṣẹ́ ẹ̀rọ ibanisọ̀rọ̀ alagbéka fún oríṣiríṣi orúkọ (16,452) ọmọ YorùbáFèsì lórí Facebook (ibùdó ayélújára afinihàn tàbí ìwé a fi ojú ẹni mọ̀ ní) |
|||||
|
Àṣẹ-lórí-àrà © 2010 Abeokuta.ORG - Gbogbo ẹ̀tọ́ wa lá di mú |
|||||
Ẹ ku isẹ nla yii o. A mọ rírì nǹkan ti ẹ n ṣe o.
Sùgbọ́n mọ rò wí pe nkan ti awọn òyìbó elèdè Gẹ̀ẹ́si pe ní “software” túmọ̀ si ‘èlò-ìṣẹ́’
Adedamọla
Ẹ ṣe púpọ̀ Alàgbá Adédàmọ́lá fún èsì yin, inú wa dún láti gbọ́ éró ọkàn yin nipa ọ̀rọ̀ yi.
Ojú ìwé 396 ìwé ìtúmọ̀ Ọ̀jọ̀gbọ́n Káyọ̀dé. Y. Fákinlẹde láti rí pe wọn túmọ
nkan ti awọn elèdè Gẹ̀ẹ́si pe ní “software” si àwo-idaríi kọ̀mpútà .
Amazon
Google
Ṣùgbọ́n lẹ́hìn ìgbà a ti gbọ́ aláàyè yin, àti yi àkọlé ọ̀rọ̀ yi padà si èlò-ìṣẹ́ gẹ́gẹ́bíi ìmọ̀ràn yin.
Ẹ ṣe, adúpẹ́!
Ẹ ku isimi, mo fẹ ran yin leti lati ṣe afilọ Yoruba gbode lori ẹrọ ayélújára (èyí ti a npe ni “internet” ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) ni ipade àṣà Yoruba (èyí ti a npe ni “Heritage” ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) ti oṣoṣu, ‘Dọlápọ̀