láti ọwọ́ Ajialàrà
Irú ìgbésí ayé wo ní Obìnrin wà?
Obìnrin ní ìyá wá, olùrànlọ́wọ́, alábarò, ọ̀rẹ́, àbúrò, ẹ̀gbọ́n àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ.
Wo àyíká rẹ̀ ki o sọ fún mi ipò ti obìnrin wá nínú ayé rẹ̀?
Gẹ́gẹbi Obìnrin, a o maa wo ní ìpele ní ìpele gbogbo nkan ti Obìnrin fi jẹ́ Obìnrin.
Ní ọ̀sẹ̀ to ḿbọ̀, a o sọ̀rọ̀ nípa Obìnrin gẹ́gẹ́bi Ìyá wà.
Ẹ kábọ̀ o, si “Ayé Obìnrin“.
Ní agbára Olódùmarè a o pàdé ní ọ̀sẹ̀ to mbọ.
Ẹ kú ojú lọ̀nà o.
Èmi ní tiyín nitòótọ́, Ajialàrà.
Pín káàkiri:
Èrò ọkàn ènìyàn kanṣoṣo nípa Ayé Obìnrin (ọ̀rọ̀ àsọṣaájú)
Ẹ ṣe púpọ̀ Arábìnrin Ajialàrà!
Inú wa dùn púpọ̀ nípa ẹ̀ka titun ti ẹ dá sílẹ̀ lórí ayélújára yí, èyí ti ẹ pe ni “Ayé Obìnrin”.
Ẹ̀ka titun yi pẹ̀lú ẹ̀ka “Ẹ̀tọ́ Obìnrin” ti o ti wà tẹ́lẹ̀ lórí ayélújára yí,
fi hàn bi ipò Obinrin ṣe jẹ pàtàkì lórí ayélújára yí, àti ní ilẹ̀ Yorùbá.
Ẹ kabọ̀!
Ẹ fi àwọn ìka òòtẹ̀-ìwé wa, kọ̀ èrò ọkàn yín, nípa ọ̀rọ̀ yìí