Ìlànà òòtẹ̀ẹ-oúnjẹ

usda_logo_rev1. Kíni ìlànà òòtẹ̀ẹ-oúnjẹ? 2. Njẹ mó lé gba awọn ànfàní òòtẹ̀ẹ-oúnjẹ yí? 3. Bàwó ní mo ṣé lé béèrè fùn ànfàní òòtẹ̀ẹ-oúnjẹ yí?
4. Bàwó ní mo ṣe lé wá ilé ìṣé àgbèègbè mí rí?
5. Njẹ mo ní làti ní nùmbá “social security”?
6. Njẹ mo leè rí awọn ànfàní òòtẹ̀ẹ-oúnjẹ yí gba láìní ni ìṣé lọwọ? 7. Njẹ ẹní àjèjì tí o ní ìwé ìgbélú t’olófin leè rí ìrànlọwọ yí gba?
8. Níbó ní mo tí leè rí àlàyé lẹkùnrẹrẹ gba?
9. Bàwo ní ìdílé mi ṣé leè jẹun dada?

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter

Ìwà-ipá nínú ilé

Ìwà-ipá nínú ilé, pàtàkì láti ọwọ́ ẹnití ti o jẹ alábagbé, ọrẹ́ tàbí ọkọ rẹ̀, le ṣẹlè si ẹ̀nikẹ̀ni, láìbìkítà fún ìpò ti ènìyàn wà, tàbí ẹ̀gbẹ́, tàbí ọjọ́ orí, obìnrin tàbí ọkùnrin, ẹsìn, bọ́yá ènìyàn ni abùku ará tàbí áwọ̀ ènìyàn.

Ìtọ́ka sí ìparí – Ìwà-ipá nínú ilé »

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter

ISẸ́ ÈTÒ ÌLERA ÌJỌBA ÀPAPỌ̀

logo_nhs
Báwo ní mo ṣe lè ri ìrànlọ́wọ́ gba fún àìlera mi?
Báwo ní mo ṣe lè ṣètò làti rí dókítà?
Bi nko ba gbọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì nkọ́?
Taní o tún nba GP mí ṣiṣẹ?
Bi mo bá fẹ́ ri dókítà ti o ni imọ̀ pàtàkì nipa àìsàn ti nṣe mí nkọ́?
Taní o tún lè ràn mi lọ́wọ́?
Nigbati a bá ti ti ilẹ̀kùn ilé-ìwòsàn GP rẹ̀
Ohun ti o lè ṣe nigba pajawiri
Ìwé ti a nkọ́ àrùn ti nṣe ni sí
.

Ìtọ́ka sí ìparí – ISẸ́ ÈTÒ ÌLERA ÌJỌBA ÀPAPỌ̀ »

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter

Ètò ẹ̀kọ́ ní èdè àbínibí fún akẹ́kọ̀ọ́ ní orílẹ̀-èdè Kánádà

Báwo ní òye èdè àbínibí ṣe nran ọmọ mi lọ́wọ́ làti kọ́ èdè Òyìnbó?
Báwo ní mo ṣe le lo èdè àbínibí mi làti ran ẹ̀kọ́ ọmọ mi lọ́wọ́?
Kíni ìdí ti mo ní làti ka àwọn ìwé èdè méjì pẹ̀lú ọmọ mi?
Báwo ní mo ṣe le lo ìwé èdè méjì pẹ̀lú ọmọ mi?
Nìbó ní mo tún ti le mọ̀ nípá èdè míràn yi?

Ìtọ́ka sí ìparí – Ètò ẹ̀kọ́ ní èdè àbínibí fún akẹ́kọ̀ọ́ ní orílẹ̀-èdè Kánádà »

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter

Ẹkún ìjọba Lambeth

Ìtọ́ka sí ìwé ní èdè Yorùbá lati láti ọwọ́ ẹkún ìjọba Lambeth

Ìwé-ẹ̀rí fun ètò ẹ̀kọ́ Yorùbá ni orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì (UK)

Ìtọ́ka sí Ìwé-ẹ̀rí fun ètò ẹ̀kọ́ Yorùbá ni orílẹ̀-èdè Gẹ̀ẹ́sì (UK):

1. Ìwé-ẹ̀rí kíní

2. Ìwé-ẹ̀rí kéjì

Pín káàkiri:
  • Facebook
  • Twitter