Gbogbo wa mọ̀ wípé òńkọ̀wé Mark Twain jẹ́ ọkan nínú àwọn òńkọ̀wé pàtàkì nínú ilẹ̀ Amẹ́ríkà, gẹ́gẹ́bí William Shakespeare ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì tàbí Bàbá D.O. Fágúnwà ní ilẹ̀ Yorùbá. Ṣugbọn púpọ̀ nínú wa ní kò mọ̀ wípé Mark Twain pa òwe Yorùbá méjì nínú ìwé ti wọ́n kọ ni ọdún 1915, èyí ti akọ́lé rẹ̀ (ni èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ “The gilded age: tale of to-day, Volume 2″.
Tá ló mọ̀ ìtumọ́ àwọn òwe méjì náà? Àwọn òwe yìí wá ní ojú ìwé 194 nínú ìwé náà.
Ìtọ́ka sí ìparí – Mark Twain pa òwe Yorùbá méjì »



Òwe òní rán mi létí ìjọba Olóyè Ernest Ṣónẹ́kàn ní ọdún 1993 ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.
Èsì àwọn ènìyàn
09/02/2010 (7:53) Mark Twain pa òwe Yorùbá méjì
08/30/2010 (12:06) Ta ló mọ ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ yìí?
08/07/2010 (11:08) Ta ló mọ ìtúmọ̀ àwọn ọ̀rọ̀ yìí?
07/03/2010 (11:58) Traducción de Español a Yoruba
07/02/2010 (6:19) Ẹ dá sọ̀rọ̀ yìí : Òfin ìjọba nípa àṣà kikọ ìlà si ojú ọmọdé?
06/23/2010 (6:06) Ẹ dá sọ̀rọ̀ yìí : Njẹ́ o yẹ ki ọkùnrin máa dí irun bi?
06/21/2010 (1:45) Idamu Alárinà : Kíni ki nṣe? (Apá kẹ́ta)
06/18/2010 (9:56) Ìdíje bọ́ọ̀lù afẹsẹ̀gbá àgbáyé
06/08/2010 (10:41) Ẹ dá sọ̀rọ̀ yìí : Òfin ìjọba nípa àṣà kikọ ìlà si ojú ọmọdé?
06/06/2010 (10:49) Ẹ̀wà: Oúnjẹ ìbéjì