|
|
Orin ti wọn gbọ ni Opo Ọmọ lehin KRISTI ti Radio Abẹokuta
Orin ti wọn gbọ bayi lori Opo kini ti Radio Abẹokuta
Radio Abẹokuta je gẹgẹ bi Ile Akede asọrọmagbesi lori Itakun agbaaye fun igbega orin ni èdè Yoruba. Gbogbo orin ti won ti n gbọ lori RADIO ABẸOKUTA lati ọjọ ti a ti da sile, ni ọjọ kefa osu keji ọdun 2002, lati san owo fun iwe eri (ti awọn oloyinbo Gẹẹsi pe ni "royalties & licensing fees") fun ajọ Live365 - ibudo atakun to ni aşe lati ọwọ ajọ orin bi ASCAP, BMI & SESAC.
|
ADANWO LORI ẸRỌ SATELLITE
ALABASEPỌ FUN AŞA IBILẸ
|